Oramipada

O ra mi pada aa/2x
Lowo esu, lowo ese, lowo iku

Iye mi wa ninu re e/2x
Moriiye gba, moriiye gba,
Ayo mi kun

Iku oro re daa
Isa oku isegun re daa

O gba kokoro lowo iku
Ogbe iku mi niisegun