O ra mi pada aa/2x Lowo esu, lowo ese, lowo iku
Iye mi wa ninu re e/2x Moriiye gba, moriiye gba, Ayo mi kun
Iku oro re daa Isa oku isegun re daa
O gba kokoro lowo iku Ogbe iku mi niisegun